Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremáyà 37:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Èyí ni, ohun tí Olúwa Ọlọ́run àwọn Ísírẹ́lì sọ fún Ọba àwọn Júdà tó rán ọ láti wádìí nípa mi. ‘Àwọn ọmọ ogun Fáráò tó jáde láti kún ọ lọ́wọ́ yóò padà sílẹ̀ wọn sí Éjíbítì.

Ka pipe ipin Jeremáyà 37

Wo Jeremáyà 37:7 ni o tọ