Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremáyà 37:1-2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

1. Sedekáyà ọmọ Jòsáyà sì jọba nípò Kóráyà ọmọ Jéhóíákímù ẹni tí Nebukadinésárì Ọba Bábílónì fi jẹ Ọba ní ilẹ̀ Júdà.

2. Ṣùgbọ́n àti òun àti àwọn ìránṣẹ́ rẹ̀ àti àwọn ènìyàn ilẹ̀ náà kò fetísí ọ̀rọ̀ Olúwa tí ó sọ nípa wòlíì Jeremáyà.

Ka pipe ipin Jeremáyà 37