Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremáyà 35:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Mo sì mú wọn wá sí ilé Olúwa sínú iyàrá Hanani ọmọ Ígídálíà, ènìyàn Ọlọ́run, tí ó wà lẹ́bàá yàrá àwọn ìjòyè, tí ó wà ní òkè yàrá Mááséíà, ọmọ Sálúmù, olùtọ́jú ẹnu-ọ̀nà,

Ka pipe ipin Jeremáyà 35

Wo Jeremáyà 35:4 ni o tọ