Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremáyà 33:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Èyí ni ohun tí Olúwa àwọn ọmọ ogun wí, ‘Ní ilẹ̀ yìí tí ó ti dahoro láìsí ọkùnrin àti àwọn ẹran nínú gbogbo ìlú, kò ní sí pápá oko fún àwọn olùṣọ́ àgùntàn láti mú àwọn ẹran ọ̀sìn wọn sinmi.

Ka pipe ipin Jeremáyà 33

Wo Jeremáyà 33:12 ni o tọ