Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremáyà 32:44 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wọn ó fi owó fàdákà ra oko, wọn yóò fi ọwọ́ sí ìwé, wọn ó dí i pa pẹ̀lú ẹlẹ́rìí láti ilẹ̀ Bẹ́ńjámínì àti ní ìlú kékèké tí ó yí Jérúsálẹ́mù ká àti ní ìlú Júdà àti ní ìlú ọwọ́ òkè orílẹ̀ èdè ní ìhà gúṣù olókè ilẹ̀ àti ní Gúsù, nítorí èmi ó mú ìgbékùn wọn padà wá, ni Olúwa wí.”

Ka pipe ipin Jeremáyà 32

Wo Jeremáyà 32:44 ni o tọ