Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremáyà 32:39 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èmi ó fún wọn ní ọkàn kan àti ìṣe kí wọn kí ó lè máa bẹ̀rù mi fún rere wọn àti fún rere àwọn ọmọ wọn tí ó tẹ̀lé wọn.

Ka pipe ipin Jeremáyà 32

Wo Jeremáyà 32:39 ni o tọ