Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremáyà 32:33 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wọ́n kọ ẹ̀yìn sími, wọ́n sì yí ojú wọn padà. Èmi kọ̀ wọ́n, síbẹ̀ wọn kò fetísílẹ̀ láti gbọ́ ẹ̀kọ́ tàbí kọbiara sí ìwà ìbàjẹ́.

Ka pipe ipin Jeremáyà 32

Wo Jeremáyà 32:33 ni o tọ