Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremáyà 32:24 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Wò ó, bí àwọn ìdọ̀tí ṣe korájọ láti gba ìlú. Nítorí idà, ìyàn àti àjàkálẹ̀-àrùn, sì fi ìlú lé ọwọ́ àwọn ará Kálídéà tí ń gbógun tì wọ́n. Ohun tí ìwọ sọ ṣẹ gẹ́gẹ́ bí o ṣe rí i.

Ka pipe ipin Jeremáyà 32

Wo Jeremáyà 32:24 ni o tọ