Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremáyà 32:15 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nítorí èyí ni ohun tí Olúwa àwọn ọmọ-ogun Ọlọ́run Ísírẹ́lì wí; àwọn ilẹ̀, pápá àti ọgbà àjàrà ni à ó tún rà padà nílẹ̀ yìí.

Ka pipe ipin Jeremáyà 32

Wo Jeremáyà 32:15 ni o tọ