Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremáyà 32:1-2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

1. Èyí ni ọ̀rọ̀ tó tọ Jeremáyà wá láti ọ̀dọ̀ Olúwa ní ọdún kẹwàá sédékáyà Ọba Júdà, èyí tí ó jẹ́ ọdún kejìdínlógún ti Nebukadinésárì.

2. Àwọn ogun Ọba Bábílónì ìgbà náà há Jérúsálẹ́mù mọ́. A sì ṣé wòlíì Jeremáyà mọ́ inú túbú tí wọ́n ń sọ́ ní àgbàlá ilé Ọba Júdà.

Ka pipe ipin Jeremáyà 32