Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremáyà 31:32 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Kò ní dàbí májẹ̀mútí mo bá àwọn baba ńlá wọn dá,nígbà tí mo fà wọ́n lọ́wọ́,tí mo mú wọn jáde ní Éjíbítìnítorí wọ́n da májẹ̀mú mi.Lóòótọ́ ọkọ ni èmi jẹ́ fún wọn,”ni Olúwa wí.

Ka pipe ipin Jeremáyà 31

Wo Jeremáyà 31:32 ni o tọ