Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremáyà 30:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“ ‘Ní ọjọ́ náà,’ Olúwa wí pé;‘Èmi yóò gbé àjàgà kúrò lọ́rùn wọn,Èmi yóò sì tú ìdè wọn sọnù.Àwọn alejo kì yóò sì mú ọ sìn wọ́n mọ́

Ka pipe ipin Jeremáyà 30

Wo Jeremáyà 30:8 ni o tọ