Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremáyà 30:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Béèrè kí o sì rí:Ǹjẹ́ ọkùnrin le dá ọmọ bí?Èéṣe tí mo fi ń rí àwọn alágbára ọkùnrintí wọ́n fi ọwọ́ wọn mú inú wọn bí obìnrin tó ń rọbí,tí ojú gbogbo wọn sì fàro fún ìrora?

Ka pipe ipin Jeremáyà 30

Wo Jeremáyà 30:6 ni o tọ