Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremáyà 30:15 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èéṣe tí ẹ̀yin fi ń kígbe nítorí ọgbẹ́ yín,ìrora yín èyí tí kò ní oògùn?Nítorí ọ̀pọ̀ ẹ̀ṣẹ̀ yín àti ẹ̀bi yín tó gani mo fi ṣe àwọn nǹkan wọ̀nyí sí i yín.

Ka pipe ipin Jeremáyà 30

Wo Jeremáyà 30:15 ni o tọ