Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremáyà 3:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nítorí náà, a ti fa ọ̀wàrà òjò sẹ́yìn,kò sì sí òjò àrọ̀kúrò.Síbẹ̀ ìwọ ní ojú líle ti panṣágà,ìwọ sì kọ̀ láti ní ìtìjú.

Ka pipe ipin Jeremáyà 3

Wo Jeremáyà 3:3 ni o tọ