Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremáyà 3:21 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

A gbọ́ ohùn àgàn láti ibi gíga,ẹkún àti ẹ̀bẹ̀ àwọn ọmọ Ísírẹ́lì,nítorí wọ́n ti yí ọ̀nà wọn po,wọ́n sì ti gbàgbé Olúwa Ọlọ́run wọn.

Ka pipe ipin Jeremáyà 3

Wo Jeremáyà 3:21 ni o tọ