Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremáyà 3:17 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní ìgbà náà, wọn yóò pe Jérúsálẹ́mù ní ìtẹ́ Olúwa gbogbo orílẹ̀ èdè yóò péjọ sí Jérúsálẹ́mù láti bọ̀wọ̀ fún orúkọ Olúwa, wọn kì yóò sì tún tẹ̀lé àyà líle burúkú wọn mọ́.

Ka pipe ipin Jeremáyà 3

Wo Jeremáyà 3:17 ni o tọ