Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremáyà 29:31 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Rán iṣẹ́ yìí sí gbogbo àwọn àtìpó: ‘Èyí ni ohun tí Olúwa sọ nípa Ṣemáyà àti Neelamaiti: Nítorí pé Semaíà ti sọ tẹ́lẹ̀ fún un yín, súgbọ́n èmi kò ran an, tí òun sì ń mú u yín gbẹ́kẹ̀lé èké.

Ka pipe ipin Jeremáyà 29

Wo Jeremáyà 29:31 ni o tọ