Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremáyà 29:19 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nítorí wọ́n kọ̀ láti fetí sí ọ̀rọ̀ mi,” ni Olúwa Ọlọ́run wí. Ọ̀rọ̀ tí mo tún ti ẹnu àwọn ìránṣẹ́ mi wòlíì sọ ni ẹ̀yin tí ń ṣe àtìpó kò gbọ́ ni Olúwa Ọlọ́run wí.

Ka pipe ipin Jeremáyà 29

Wo Jeremáyà 29:19 ni o tọ