Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremáyà 28:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní ìbẹ̀rẹ̀ àwọn wòlíì tí ó ṣáájú rẹ àti èmi ti sọ àsọtẹ́lẹ̀ ogun, ibi àti àjàkálẹ̀ sí ọ̀pọ̀ orílẹ̀ èdè.

Ka pipe ipin Jeremáyà 28

Wo Jeremáyà 28:8 ni o tọ