Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremáyà 28:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó sọ wí pé, “Àmín! Kí Olúwa ó ṣe bẹ́ẹ̀! Kí Olúwa ó mú àwíṣẹ àsọtẹ́lẹ̀ nípa ohun èlò ilé Olúwa àti gbogbo àwọn aṣàtìpó padà sí ilẹ̀ Bábílónì.

Ka pipe ipin Jeremáyà 28

Wo Jeremáyà 28:6 ni o tọ