Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremáyà 28:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èmi á tún mú àyè Jéhóíákínì ọmọ Jéhóíákímù Ọba Júdà padà, àti gbogbo àwọn tí ń ṣe àtìpó láti Júdà ní Bábílónì,’ èyí ni ọ̀rọ̀ Olúwa pé, ‘àjàgà yín láti ọwọ́ Ọba Bábílónì yóò rọrùn.’ ”

Ka pipe ipin Jeremáyà 28

Wo Jeremáyà 28:4 ni o tọ