Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremáyà 28:16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nítorí náà, èyí ni ohun tí Olúwa wí: ‘Mo ṣetán láti mú ọ kúrò nínú ayé, ní ọdún yìí ni ìwọ yóò kú nítorí o ti wàásù ọ̀tẹ̀ sí Olúwa.’ ”

Ka pipe ipin Jeremáyà 28

Wo Jeremáyà 28:16 ni o tọ