Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremáyà 27:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“ ‘ “Àmọ́ tí orílẹ̀ èdè tàbí ìjọba kan kò bá ní sin Nebukadinésárì Ọba Bábílónì, tàbí kí ó tẹ orí rẹ̀ ba ní abẹ́ àjàgà rẹ̀; Èmi yóò fi ìyà jẹ orílẹ̀ èdè náà nípa idà, ìyàn àti àjàkálẹ̀-àrùn, ni Olúwa wí títí Èmi yóò fi run wọ́n nípa ọwọ́ rẹ̀.

Ka pipe ipin Jeremáyà 27

Wo Jeremáyà 27:8 ni o tọ