Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremáyà 27:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èmi sì sọ ọ̀rọ̀ náà fún Sedekáyà Ọba Júdà wí pé: “Tẹ orí rẹ ba lábẹ́ àjàgà Ọba Bábílónì, sìn ín ìwọ àti àwọn ènìyàn rẹ, ìwọ yóò sì yè.

Ka pipe ipin Jeremáyà 27

Wo Jeremáyà 27:12 ni o tọ