Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremáyà 26:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Kí ló dé tí ìwọ ṣe sọ àṣọtẹ́lẹ̀ ní orúkọ Olúwa pé, ilé yìí yóò dàbí ṣílò, orílẹ̀ èdè yìí yóò sì di ahoro tí kì yóò ní olùgbé.” Gbogbo àwọn ènìyàn sì kójọpọ̀ pẹ̀lú Jeremáyà nínú ilé Olúwa.

Ka pipe ipin Jeremáyà 26

Wo Jeremáyà 26:9 ni o tọ