Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremáyà 25:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Ṣùgbọ́n ẹ̀yin kò fetí sí mi,” ni Olúwa wí; “bẹ́ẹ̀ ni ẹ sì ti mú inú bí mi pẹ̀lú ohun tí ẹ fi ọwọ́ yín ṣe, ẹ sì ti mú ibi wá sórí ara yín.”

Ka pipe ipin Jeremáyà 25

Wo Jeremáyà 25:7 ni o tọ