Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremáyà 25:38 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Gẹ́gẹ́ bí kìnnìún yóò fi ibùba rẹ̀ sílẹ̀,ilẹ̀ wọn yóò sì di ahoro, nítorí idà àwọn anínilára,àti nítorí ìbínú ńlá Olúwa.

Ka pipe ipin Jeremáyà 25

Wo Jeremáyà 25:38 ni o tọ