Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremáyà 25:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Fún odidi ọdún mẹ́talélógún, bẹ̀rẹ̀ láti ọdún kẹtàlá Jòsáyà, ọmọ Ámónì Ọba Júdà, títí di ọjọ́ yìí, ọ̀rọ̀ Olúwa sì tọ̀ mí wá, mo sì ti sọ ọ́ fún un yín láti ìgbà dé ìgbà, àmọ́ ẹ̀yin kò fetí sílẹ̀.

Ka pipe ipin Jeremáyà 25

Wo Jeremáyà 25:3 ni o tọ