Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremáyà 25:28 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ṣùgbọ́n bí wọ́n ba kọ̀ láti gba aago náà ní ọwọ́ rẹ kí wọ́n sì mu ún, sọ fún wọn pé, ‘Èyí ni ohun tí Ọlọ́run alágbára sọ: Ẹyin gbọdọ̀ mu ún!

Ka pipe ipin Jeremáyà 25

Wo Jeremáyà 25:28 ni o tọ