Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremáyà 25:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èmi yóò sì mú ìró ayọ̀ àti inú dídùn kúrò lọ́dọ̀ wọn; ohùn ìyàwó àti ọkọ ìyàwó, ìró ọlọ òkúta àti ìmọ́lẹ̀ fìtílà.

Ka pipe ipin Jeremáyà 25

Wo Jeremáyà 25:10 ni o tọ