Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremáyà 24:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èmi yóò sọ wọ́n di ìwọ̀sí àti ẹni ibi sí gbogbo ìjọba ayé, ẹni ẹ̀sín àti ẹni ẹ̀tẹ́, ẹni àbùkù àti ẹni èpè ní ibi gbogbo tí Èmi bá lé wọn sí.

Ka pipe ipin Jeremáyà 24

Wo Jeremáyà 24:9 ni o tọ