Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremáyà 24:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ojú mi yóò máa ṣọ́ wọn lọ fún rere; Èmi yóò gbé wọn ró, n kò ní já wọn lulẹ̀. Èmi yóò gbìn wọ́n, n kò sì ní fà wọ́n tu.

Ka pipe ipin Jeremáyà 24

Wo Jeremáyà 24:6 ni o tọ