Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremáyà 22:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ìdáhùn wọn yóò sì jẹ́: ‘Nítorí tí wọ́n ti kọ májẹ̀mú Olúwa Ọlọ́run wọn sílẹ̀, wọn ti ń fi oríbalẹ̀ fún Ọlọ́run mìíràn, wọ́n sì sìn wọ́n.’ ”

Ka pipe ipin Jeremáyà 22

Wo Jeremáyà 22:9 ni o tọ