Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremáyà 22:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nítorí báyìí ni Olúwa wí, nípa ààfin Ọba Júdà,“Bí ó tilẹ̀ jẹ́ wí pé ìwọ dàbí Gílíádì sí mi,gẹ́gẹ́ bí góńgó òkè Lẹ́bánónì,dájúdájú Èmi yóò sọ ọ́ di aṣálẹ̀,àní gẹ́gẹ́ bí ìlú tí a kò gbé inú wọn.

Ka pipe ipin Jeremáyà 22

Wo Jeremáyà 22:6 ni o tọ