Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremáyà 22:30 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Báyìí ni Olúwa wí:“Kọ àkọsílẹ̀ ọkùnrin yìí sínú ìwé gẹ́gẹ́ bí aláìlọ́mọ,ẹni tí kì yóò ṣe rere ní ọjọ́ ayé rẹ̀;nítorí ọ̀kan nínú irú ọmọ rẹ̀ kì yóò ṣe rere,èyíkéyìí wọn kì yóò jókòó lórí ìtẹ́ Dáfídìtàbí jọba ní Júdà mọ́.”

Ka pipe ipin Jeremáyà 22

Wo Jeremáyà 22:30 ni o tọ