Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremáyà 22:26 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èmi ó fi ìwọ àti ìyá tí ó bí ọ sọ̀kò sí ilẹ̀ mìíràn, níbi tí a kò bí ẹnikẹ́ni nínú yín sí. Níbẹ̀ ni ẹ̀yin méjèèjì yóò kú sí.

Ka pipe ipin Jeremáyà 22

Wo Jeremáyà 22:26 ni o tọ