Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremáyà 22:24 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Dájúdájú bí èmi ti wà láàyè,” ni Olúwa wí, “Bí Jéhóíákínì ọmọ Jéhóíákímù Ọba Júdà tilẹ̀ jẹ́ òrùka èdìdì lọ́wọ́ ọ̀tún mi, síbẹ̀ èmi ó fà ọ́ tu kúrò níbẹ̀.

Ka pipe ipin Jeremáyà 22

Wo Jeremáyà 22:24 ni o tọ