Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremáyà 20:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbàkúgbà tí mo bá sọ̀rọ̀, èmi sì kígbe sítaèmi á sọ nípa ipá àti ìparun.Nítorí náà, ọ̀rọ̀ Olúwa ti mú àbùkùàti ẹ̀gàn bá mi ni gbogbo ìgbà.

Ka pipe ipin Jeremáyà 20

Wo Jeremáyà 20:8 ni o tọ