Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremáyà 20:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àti ìwọ Páṣúrì, gbogbo ènìyàn inú ilé rẹ yóò sì lọ ṣe àtìpó ní Bábílónì. Níbẹ̀ ni ìwọ yóò sì kú sí, tí wọn yóò sì sin ọ́ síbẹ̀, ìwọ àti gbogbo àwọn ọ̀rẹ́ rẹ tí ìwọ ti sọ àṣọtẹ́lẹ̀ irọ́ fún.”

Ka pipe ipin Jeremáyà 20

Wo Jeremáyà 20:6 ni o tọ