Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremáyà 20:16-18 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

16. Kí ọkùnrin náà dàbí ìlútí Olúwa gbàkóso lọ́wọ́ rẹ̀ láìkáànúKí o sì gbọ́ ariwo ọ̀fọ̀ ní àárọ̀,ariwo ogun ní ọ̀sán.

17. Nítorí kò pa mí nínú,kí ìyá mi sì dàbí títóbi ibojì mi,kí ikùn rẹ̀ sì di títí láé.

18. Èéṣe tí mo jáde nínú ikùn,láti rí wàhálà àti ọ̀fọ̀àti láti parí ayé mi nínú ìtìjú?

Ka pipe ipin Jeremáyà 20