Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremáyà 2:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wọn kò béèrè, ‘Níbo ni Olúwa wà tí ó mú wọn,jáde láti ilẹ̀ Éjíbítì, tí ó mú wala ihà já, tí ó mu wọn la àárin àwọnaṣálẹ̀ àti òkè láàrin ìyàngbẹ ilẹ̀àti òkùnkùn wá ilẹ̀ ibi tí ẹnikẹ́nikò ti rìnrìn-àjò, tí ẹníkẹ́ni kò sì gbé?’

Ka pipe ipin Jeremáyà 2

Wo Jeremáyà 2:6 ni o tọ