Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremáyà 2:34-36 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

34. Lórí aṣọ rẹ ni wọ́n bá ẹ̀jẹ̀àwọn talákà aláìṣẹ̀bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé kò ká wọnníbi tí wọ́n ti ń rùn wọlé

35. Ṣíbẹ̀ nínú gbogbo èyíìwọ sọ wí pé, ‘Èmi jẹ́ aláìsẹ̀kò sì bínú sími.’Èmi yóò ṣe ìdájọ́ mi lórí rẹnítorí pé ìwọ sọ pé, ‘Èmi kò tí ìdẹ́sẹ̀.’

36. Kí ló dé tí o fi ń lọ káàkiriláti yí ọ̀nà rẹ padà?Éjíbítì yóò dójú tì ọ́gẹ́gẹ́ bí i ti Ásíríà

Ka pipe ipin Jeremáyà 2