Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremáyà 2:27 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wọn sọ fún igi pé, ‘Ìwọ ni bàbá mi,’àti sí òkúta wí pé, ‘Ìwọ ni ó bí mi,’wọ́n ti kọ ẹ̀yìn wọn sí mi, wọn kò kọojú sí mi ṣíbẹ̀ nígbà tí wọ́nbá wà nínú ìṣòro, wọn yóòwí pé, ‘Wá kí o sì gbà wá!’

Ka pipe ipin Jeremáyà 2

Wo Jeremáyà 2:27 ni o tọ