Má ṣe sáré títí ẹṣẹ̀ yín yóò fi wà ní ìhòòhò,tí ahọ́n yín yóò sì gbẹ.Ṣùgbọ́n ìwọ wí pé, ‘Kò nílò!Èmi fẹ́ràn àwọn ọlọ́run àjèjì,èmi yóò sì lépa wọn lọ.’