Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremáyà 2:23 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Báwo ni o ṣe le lọ sọ pé, ‘Èmi kò ṣe aláìmọ́;Èmi kò ṣáà tẹ̀lé àwọn Báálì’?Wo bí o ṣe hùwà ní àfonífojì;wo ohun tí o ṣe.Ìwọ jẹ́ abo ìbákasíẹ̀tí ń sá sí ìhín sọ́hùn ún.

Ka pipe ipin Jeremáyà 2

Wo Jeremáyà 2:23 ni o tọ