Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremáyà 2:20 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Nígbà àtijọ́, o ti fọ́ àjàgàrẹ sọnù, ìwọ sì já ìdè rẹìwọ wí pé, ‘Èmi kì yóò sìn ọ́!’Lóòtọ́, lórí gbogbo òkè gíga niàti lábẹ́ igi tí ó tàn kálẹ̀ni ìwọ dùbúlẹ̀ sí gẹ́gẹ́ bí panṣágà.

Ka pipe ipin Jeremáyà 2

Wo Jeremáyà 2:20 ni o tọ