Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremáyà 18:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Ẹyin ilé Ísírẹ́lì, èmi kò ha lè ṣe fún un yín gẹ́gẹ́ bí amọ̀kòkò yìí ti ṣe?” ni Olúwa wí. “Gẹ́gẹ́ bí amọ̀ ní ọwọ́ amọ̀kòkò bẹ́ẹ̀ ni ẹ̀yin rí ní ọwọ́ mi, ẹ̀yin ilé Ísírẹ́lì.

Ka pipe ipin Jeremáyà 18

Wo Jeremáyà 18:6 ni o tọ