Ṣùgbọ́n ìwọ Olúwa mọ gbogboète wọn láti pa mí, má ṣe fojú fòibi wọn tàbí pa ẹ̀ṣẹ̀ wọn rẹ́ kúròlójú rẹ. Jẹ́ kí a mú wọn kúrò níwájú rẹbá wọn jà nígbà ìbínú rẹ.