Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremáyà 18:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Ǹjẹ́ nísìnsìnyìí, sọ fún àwọn ènìyàn Júdà àti àwọn olúgbé Jérúsálẹ́mù wí pé, ‘Báyìí ní Olúwa wí: Wò ó! Èmi ń gbérò ibi sí yin, èmi sì ń ṣe ìpinnu kan lórí yín. Nítorí náà ẹ yípadà kúrò lọ́nà búburú yín kí olúkúlúkù yín sì tún ọ̀nà àti ìṣe rè ṣe.’

Ka pipe ipin Jeremáyà 18

Wo Jeremáyà 18:11 ni o tọ